Published 12 months ago in Afropop & Afrofusion, in album: S2

Ololufe

  • 39
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0

The track "Ololufe" is particularly noteworthy. Award-winning vocalist Wande Coal contributes a sick verse to the song that flawlessly matches Wizkid's performance. Together, their voices are amazing.

Producers P Priime and Olajumoke Olayiwola deserve recognition for their skillful work on this outstanding 2023 tune. The enthralling beats and catchy melodies of "Ololufe" make it an instant hit, and their skill is evident.

Lyrics

I can't believe that she don't
And the thing I believe go
She say W mo cold
O wa sọpẹ W mi o cold o (P!)
Wanna be on your show
Wanna put me on your shoulder
Layẹmi, sọfun wọn mo n'ifé, mo n'ife e gan ni
Fine lady girl you different, you different gan ni o
I no know why but mo miss ẹ, mo miss ẹ gan ni o
Bad girl I'm addicted, addicted gan ni o
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ (giddem!)
Layẹmi, Olayẹmi mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ mo n'ifẹ
Titilọla, hmm, sọ fun ẹ mo n'ifẹ
Moni Fọlashade
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ife gan ni
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ re
Ko ko ko ko
Konkobilo, ko ko ko
Ọwá fẹ pàdé mí ní ìsàlè
Òye ká fún konkobilo
Ko ko ko ko
Owa fẹ jẹ ko ko ko ko
Moni ko pàdé mí ní ìsàlè
Ìyẹn gan lo n ṣe ko ko
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)
Layẹmi, Olayẹmi mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun wọn mo n'ifẹ eh
Titilọla, hmm, so fun ẹ mo n'ifẹ
Mo ni Fọlashade
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, n'ifẹ gan ni
Gbé mi de bẹ
Gbé mi de, gbe
Gbé mi de bẹ, de bẹ
Gbe
Wọn lo wa ji (gbé mi de bẹ)
Wọn ní mo ji
Won ní pe ki mo ji
Kini mo de
Ani kí ló gbé?
Wọn ni ko lo wi
Mo ni mo de
Wọn ni mi o dé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé

::
/ ::

Queue

Clear