Published 1 year ago in Afropop & Afrofusion, in album: Tears Of The Sun

Malaika

  • 34
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0

With her unique style and mesmerizing vocals, Teni effortlessly showcases her musical prowess in "Malaika". The song is a testament to her incredible talent and ability to create infectious melodies that resonate with listeners.

Lyrics

Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa
Eli Elijah o

Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa

I'm at peace with God and at peace with myself
I surrender, I surrender
No weapon fashioned against me shall prosper
Back to sender, back to sender

Lord, I give You my heart and my soul and devotion
You give me peace of mind
And I see all Your works and the good that You are doing
Ṣebi na You change my life

Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Ọmọ
Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Ọlọrun ẹmi mimọ
Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Ọmọ
Ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Ọlọrun ẹmi mimọ

Thank You for the things that You got me through
Na only me and You
I dey cry night You dey wipe my eyes
Na You dey give me grace o
You say make I get faith o
Make my faith no deflate o

Don't jump from my plate o
People change but You remain the same o
Aimọye eeyan to n ku lojoojumọ
Mi o fi yọ wọn
Mo fi n dupẹ ni
Ẹru n dupẹ ni
Mo fi n dupẹ ni o

Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa

Eli Elijah o
Eli Elijah
Eli Elijah ah ah
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o
Malaika sọkalẹ wa

::
/ ::

Queue

Clear